E ma se je ki a ro wipe ati mo ohun gbogbo ti Olorun ti se fun wa ninu Kristi, niwon igba to je wipe a si wa ni ipo ti a ha wa si yii. E je ki a pada sinu Biblei lati ko awon eko yii.
#tregomedia #gospel #athisfeet #yorubasermon #yoruba #faith #redemption #prosperity #preaching